Ona abayo si ishoro Eda pelu adua ati abalaye

Ona abayo si ishoro Eda pelu adua ati abalaye For any kind of ur spiritual problem u can't can't act us @ Nurul Nabiy organization of Nigeria

15/09/2022

Health is wealth

08/09/2022

ilera loro health is wealth kindly share for others to Benefit

02/09/2022

*ÀLÀYÉ DIE NIPA IRAPADA ÒGO FÚN GBOGBO*

SHARE COMMENT LIKE

Púpọ ninu ẹdá nii ọrọ aiye ee síwá nii ojukan ṣoṣo yala nile ọkọ tàbí nii ọdọ aya

Njẹ iwọ mọ pé phone tii a un lo gan anilati *rebort* ee nii ìwọnba igba tii obani ìṣòro bẹ gẹgẹ nii ọrọ ayé àwa eyan jẹ

Leyin tii aba tii ùn tẹle awọn ewọ irawo wa anilati lati mase ìràpadà fún irawo wa kii ohungbogbo le ma lọ deede gẹgẹ bí àpẹẹrẹ;


*IRAWỌ ERUPE*

Púpọ ninu awọn ipin irawọ yìí oun se ikan tii koba eleda ee mu leyin tii obati jáwọ nínú iwa ibaje tii oun se kii igbiyanju lati mase ìràpadà fún irawo ee gbiyanju lati wa awọn ikan wọn yìí.

Omí òkun

Ẹyin Adìyẹ 🐓 ibilẹ 1

Aṣọ funfun ọpa meta

Gbàdúrà sinu omi okun yìí kii owa fii ẹyin yìí sinu ee leyin naa kii owa fii omi okun yìí wẹ kìí owa fii ẹyin yìí nu gbogbo arare leyin naa kii owa fii aṣọ funfun yii bora sun tii oba dii ọjọ Kejì kii olofi se saara fún afọju onibara obìnrin tabi okùnrin.

*IRAWO AFẸFẸ*

Diẹ ninu awọn gbogbo ipin iseda yii kii ùn tètè nii ìgbàgbọ nítorí pé agbara tii owa nii arawọn ju ọjọ orí wọn lo
Ọna kansoso tii odaraju fún wọn nii kii won ma bọ ẹlẹdàá wọn nitoripe pe púpọ ninu won ogun kii ùn ṣiṣe nii ara-re
Sugbon diẹ ninu wọn nii nfani lati se ìràpadà

Aṣọ funfun ọpa mefa

Àkùkọ adìyẹ 🐓

Kii onítòhún gbàdúrà sinu dede omí tii o le fiwe leyin naa kii owa fii omi yìí sanra pẹlu ọṣe lux leyin tii obati wẹ tan kii ofi adìyẹ 🐓 yìí nu gbogbo arare

*Ìkìlọ*

Odidi ọjọ mẹta nii anilati fẹ ìwé yìí leyin ọjọ kẹta awa lori adìyẹ 🐓 ati aṣọ funfun ọpa mefa se saara fún àwọn onibara okunrin tabi obinrin.

*IRAWỌ OMÍ🔥 ATI IRAWỌ INÁ💧*

orisirisi ona nii ìṣòro má ùn gba wọ inú aiye awon ipin irawo yii ounjẹ oju orun Ibalopọ loju orun ati bẹbẹ lọ.

Bíi irawo yii ba fẹ ṣe ìràpadà eniki owa awọn ikan wọn yìí.

🕯️ GIANT CANDLE FÚNFÚN 1

OMI ODO TI OUN SAN

(dede tii oletowa fiwe)

SUGAR CUBE ODIDI KAN

AṢỌ FUNFUN ỌPA MẸTA

ÀKÙKỌ ADÌYẸ 🐓

ỌSẸ JOY 🧼

KAINKAIN IBILE

Awa da gbogbo sugar yen sii inu trai pẹrẹsẹ nla kan leyin naa awa tan ina síi gbogbo 🕯️ CANDLE yen sii Arin sugar yen fun ọjọ meta leyin na awa pa ina candle yen
Sugbon anilati gbe omi odò yẹn náà sibe oooooooooo.

Anilati nii awẹ ọjọ meta.péré

leyin tii aba ti break tan kii awa kò gbogbo ajoku 🕯️ CANDLE yen sinu omi ati gbogbo sugar

Tii oba dii Agogo mejila síi àgó méta aru kii afii omi yìí wẹ sinu kòtò nla kan kii amu diẹ ninu omi yìí pẹlu.

Kii awa fii gbogbo 🕯️ CANDLE yii nu Ara pẹlu àkùkọ adìyẹ 🐓 leyin tii aba tii wẹ tan.

Aori candle yen mọlẹ pẹlu kankan ati ọsẹ ose 🧼 joy tii ati wẹ.

leyin naa kii awafi aṣọ FÚNFÚN ọpa meta yii rap gbogbo ara adìyẹ 🐓 yìí kalo gbe fún àwọn oni bara pẹlu owó 💰 pupa.

*Ìkìlọ*

*Akogbodo nii Ibalopọ (s*x ) fún odidi ọjọ meje lẹyin tii ati parí iṣẹ yìí

*Akogbodo ba ẹnikẹ́ni já fún ọjọ meje lẹyin tii oti parí iṣẹ yìí.

*Onilati nii igbele ọjọ méta leyin tii obati parí eto yii.

Ogo emi ati iwọ koni dii òkú

Call/Whatsapp 08160692685 08145110160

02/09/2022

IRAWO IRU AISAN TI YOO MA SE WON ATI IRU JAMBA TI YOO MA FE KULO WON

Aries irawo ina:

Iru awon won yi ni yo o ma sele si awon omo yi: Aairi orun sun, ori fifo, iba, apa lori tabi ni oju won, oju didun (oju won ki nsaaba riran dada ni ale), Ijamba latara ina jijo, irore (pimple), arun ibalopo.

Ta**us irawo erupe:

Onafun didun, oju fifo,eti riro, segede, orikerike ara didun, eyi ti ko ba sora yo san ara a sanju latara apoju ora ara won.

Gemini Irawo afefe:

Aisan latara eegun apa, ejika riro, ikoeefe (Asthma), iko, otutu,aya didun, kata (catarrh), lakuregbe (Rheumatism), akilolo.

Cancer irawo omi:

Eje riru. Inu did un, ikifu (indigestion), ogbe inu, igbaya didun, won ki siso dada.

Leo irawo ina:

Aisan okan didun, iba, aisan eje ara, igbe gbuuru (Diarrhoea), atogbe/Atosi, won je omo kan to ma ndaku sere, eyin didun (backache), oju didun, oyi oju, inu rirun, opa eyin.

Virgo Irawo Erupe:

Erikerike ara riro, atoka (Appendix), aikundun ounje (loss of appetite), aisan inu ifun loun (bowel problem), aisan onigbameji (cholera), airigbeya (constipation), eti didun/ aditi, ifowo bara eni sere ti ato yoo fi jade (Ma********on).

Libra irawo afefe:

Arun kindinrin, arun apooto (bladder), atogbe, arun awo ara (skin), aipeye (impotency), ibaradi didun.

Scorpoi irawo omi:

Aisan latara oti amu para, eyin riro, aisan koropon, obinrin yoo ma ri inira toba nse nkan osu (Menstrual problem dada, ogbe inu,
Ipake (rupture), airi ito to dada.

Sagittarius irawo ina:

Ori p**a, itan a ro won nigbamiran, edo didun, Typhoid, eegun ikoko idi didun, arun egba (Paralysis).

Capricorn irawo erupe:

Arun egun ara, ironu, orunkun didun, eyin didun (Toothache).

Aquarius irawo afefe:

Oju didun, isese nibi ese won mo kokose, kokose wiwu, aisan latara ki eje ma to ara ka dada, eegun eyin, paja paja

Pisces Irawo:

Arun oti mumu, ewo (boils), omo ika ese wiwu , otutu, (ki won sora lati ma jade nigba ti a ba wa ni akoko otutu, aisan nla ma nkolu won ni akoko yi), ki won kiyesi awon ogun ti ko bawon lara mu ni lilo, ode ori.

Mo be Olohun ninu ola nla re, ko sowa nibi awon aisan wonyi, ki awa na si kiyesi ara wa nipa awon aisan won yi, kia moju to ara wa, awon ti a ko wipe won yoo ma ko aisan latara oti mimu, ki won sora won gidi nibi a mu oti tabi ki won tie jina si oti papa, tori aisan nla lo ma je fun won.

Olohun lo ni imo Julo.

02/09/2022

ASIRI OSE EYONU TÍ AWON AGBA FI NDARI OORE SI Ẹ̀YÁN TÍ IKOLO Ẹ̀YÁN YIO FI PADA TESTED AND CONFIRM NI ✅

Ummmm Eku Ataro ṣe dáadáa lewa nbẹ, èmi máa nfi gbogbo ẹnu so wípé ẹyin onigbinyanju ni Ọlọ́run wa bẹẹni... Toba wuyin kie ṣe iṣẹ́ yìí tíko ba wuyin emase, ṣùgbọ́n èmi mope Mósè ìwọ̀n tímo lè ṣe láyé rẹ... . Mofe kí ẹyin ẹ̀yán mi lọ Dan àṣírí yìí wo kie lè mope Ona Abayo si ishoro Eda yàtò gedegbe sì ọ̀pọ̀lọpọ̀ ẹgbẹ́ tio wáni orí ayé lu Jara

ISE NARE 👇👇

Eso Laa pupa pupo die
A o yo egunsi inu eso laa yen patapata
A o lo papo mo ose to ba wu wa
A o wa ko ose na sinu Awo Sobi
A o gbe awo Sobi na sori osuka nile
A o wa fi ori le ose na lori
A o wa lo gbe ose na sinu oorun (sun) t**i ori yen yio fi yo mo ose na tan
A o wa sese fi owo (hand) po gbogbo re papo morawon daadaa
A o gbe ose na pamo sibikan fun ojo meta Leyin ojo meta odi Lilo niyen ooooo

LILO RE 👇

A o ma fi ose na we leyin ojo keta ni aaro kutukutu.

AKIYESI PATAKI 👇

Idi ose na ko gbodo kanle mo rara ooo.

MOfi eledumare bura funyin wipe ìṣe tio dájú nise yìí.

Dupe kio bale je fun e

For more information
08160692685-08145110160

02/09/2022

Good morning all the house today is Friday I need 10 people to ask any questions about what you are facing as a chalange and let solve it for you or call us on this line +2348160692685 or watsap us +2348145110160 we be expecting ur message or call thank you all

08/06/2022
08/05/2022
05/05/2022

Let work for you and see the miracle of God Almighty

24/04/2022

May God Almighty answer all our prayer in this month of fasting

24/04/2022

*_RAMADAN 🌙 DAY 23_*

As_Salaam Aleykun!
I pray with The might name of Allah for support and mercy for u and yours in all your Endeavours. May u experience more grace,blessings, Good Health and Favor upon.All whatever u lay ur Hard shall prosper Aameen 🙏.

Good Morning 🌄!!!
Have A Blessed Weekend!
🌹Ambassador imoleanobicares2022🌹

Address

Lagos

Telephone

+2348160692685

Website

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Ona abayo si ishoro Eda pelu adua ati abalaye posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Contact The Business

Send a message to Ona abayo si ishoro Eda pelu adua ati abalaye:

Shortcuts

Share